[](https://github.com/ellerbrock/open-source-badges/)
[
](https://join.slack.com/t/firstcontributors/shared_invite/zt-1hg51qkgm-Xc7HxhsiPYNN3ofX2_I8FA)
[](https://opensource.org/licenses/MIT)
[](https://www.codetriage.com/roshanjossey/first-contributions)
# Akọkọ ilowosi
Lati dasi nko lakoko n'le, pataki ti a ba ronu nipa asise ti a le bapade, a fe ko rorun fun awon ilowosi akoko lati le dasi
ise agbese lakoko, ise agbese yi a ko yin be ese le se, e tele ilana ni isalẹ
#### *to ba le lo pipaṣẹ, [awon ona mi re.](#Tutorials-Usin'-Other-Tools)*
e fi git sori ẹrọ [install it](https://help.github.com/articles/set-up-git/).
## orita ibi ipamọ yii
orita ibi ipamọ yii, e te ' fork bọtini' ni oke oju iwe yi, e leyi a fun yin ni daako ni accounti yin
## Dide ibi ipamọ
oya e de ibi ipamọ yi si account yin, e lo si githubu accounti yin, e te 'clone botini, ke wa te 'copy to clipboard'
.
e sii ebute in ero ise yin, e te pipaṣẹ to be a labe oro yi si:
```
git clone "ọna asopọ ' te daakọ"
```
ibi, "ọna asopọ ' te daakọ" (lai awọn ' quote iṣmiṣ) lo je ono asopo ti e dide ibi ipamo (e dide ibi ipamo ise igbesi). e wo awon atono ti tele to n be loke
oye ko ri bi:
```
git clone https://github.com/oruko yin/first-contributions.git
```
ibi `oruko yin` ni oruko githubu accounti yin. ni bi yi en didako awon akoonu ' first-contributions repository in GitHubu' si ero ise yin.
## ṣẹda ẹka
seda eka si ero, amo ko to sebe te pipaṣẹ yi si ibe
```
cd first-contributions
```
oya seda eka si pelu ' `git checkout` pipase:
```
git checkout -b
```
fun apere:
```
git checkout -b add-luke-oliff
```
(kon se dadun ki e lo "add", amo o daa fun irun nnkan bayii)
## Ṣe awọn ayipada to ṣe pataki 'n ṣe awọn ayipada yẹn
oya shi faili `Contributors.md` ninu olootu ọrọ, fi oruko re mo awon oruko to 'n wan be, ma fe se akoko tabi igbeyn, fi si arin.
to ba te pipase `git status` si ebute re, wa re awon ayipada ti ose
fi won mo eka ti ode pelu pipase yii `git add`:
```
git add Contributors.md
```
oya dawon papop pelu pipase yi `git commit`:
```
git commit -m "Add to Contributors list"
```
yi `` pada si oruko re.
## Titari awọn ayipada si GitHub
te pipase yi `git push`:
```
git push origin
```
yi `` pada si orku e da ti ese ni ibere
## Fi yer ayipada fer awotẹlẹ
Ti o ba lọ t' yer ibi ipamọ lori GitHub, iwọ yoo ri a `Compare & pull request` botini. te botini yen.
oya fi silẹ.
To ba ya a ma so gbogo yipada ti e se papo, e o gba iwifunni lori imeeli yin
## Nibo ni lati lọ?
Ku ise oti pari boṣewa bisesenlo _fork -> clone -> edit -> PR_ bisesenlo ti o ma bapade ni ise asowopo
Ṣe ayẹyẹ ilowosi yer 'ki o pin pẹlu' awọn ọkan ati awọn ọmọlẹyin nipasẹ lilọ’ si [web app](https://roshanjossey.github.io/first-contributions/#social-share).
Ẹ lè darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ òṣìṣẹ́ wa tí kò já fáfá tí ẹ bá nílò ìrànlọ́wọ́ èyíkéyìí tàbí kí ẹ lè gba àlọ́ kankan. [Darapo](https://join.slack.com/t/firstcontributors/shared_invite/zt-1hg51qkgm-Xc7HxhsiPYNN3ofX2_I8FA).
Bayi jẹ ki a bẹrẹ pẹlu' idasi' t' awọn iṣẹ akanṣe miiran. A ti ṣe akojọpọ awọn iṣẹ akanṣe pẹlu awọn ọran irọrun ti o le bẹrẹ. Ṣayẹwo [awon re](https://roshanjossey.github.io/first-contributions/#project-list).
### [Ptu le ka](../additional-material/git_workflow_scenarios/additional-material.md)
## Tutorial lilo 'miiran Irinṣẹ
|
|
|
|
|
|
|
| --- | --- | --- | --- | --- | --- |
| [GitHub Desktop](../gui-tool-tutorials/github-desktop-tutorial.md) | [Visual Studio 2017](../gui-tool-tutorials/github-windows-vs2017-tutorial.md) | [GitKraken](../gui-tool-tutorials/gitkraken-tutorial.md) | [Visual Studio Code](../gui-tool-tutorials/github-windows-vs-code-tutorial.md) | [Atlassian Sourcetree](../gui-tool-tutorials/sourcetree-macos-tutorial.md) | [IntelliJ IDEA](../gui-tool-tutorials/github-windows-intellij-tutorial.md) |