[![Open Source Love](https://badges.frapsoft.com/os/v1/open-source.svg?v=103)](https://github.com/ellerbrock/open-source-badges/) [](https://join.slack.com/t/firstcontributors/shared_invite/zt-1hg51qkgm-Xc7HxhsiPYNN3ofX2_I8FA) [![License: MIT](https://img.shields.io/badge/License-MIT-green.svg)](https://opensource.org/licenses/MIT) [![Open Source Helpers](https://www.codetriage.com/roshanjossey/first-contributions/badges/users.svg)](https://www.codetriage.com/roshanjossey/first-contributions) # Akọkọ ilowosi Lati dasi nko lakoko n'le, pataki ti a ba ronu nipa asise ti a le bapade, a fe ko rorun fun awon ilowosi akoko lati le dasi ise agbese lakoko, ise agbese yi a ko yin be ese le se, e tele ilana ni isalẹ #### *to ba le lo pipaṣẹ, [awon ona mi re.](#Tutorials-Usin'-Other-Tools)* fork this repository e fi git sori ẹrọ [install it](https://help.github.com/articles/set-up-git/). ## orita ibi ipamọ yii orita ibi ipamọ yii, e te ' fork bọtini' ni oke oju iwe yi, e leyi a fun yin ni daako ni accounti yin ## Dide ibi ipamọ clone this repository oya e de ibi ipamọ yi si account yin, e lo si githubu accounti yin, e te 'clone botini, ke wa te 'copy to clipboard' . e sii ebute in ero ise yin, e te pipaṣẹ to be a labe oro yi si: ``` git clone "ọna asopọ ' te daakọ" ``` ibi, "ọna asopọ ' te daakọ" (lai awọn ' quote iṣmiṣ) lo je ono asopo ti e dide ibi ipamo (e dide ibi ipamo ise igbesi). e wo awon atono ti tele to n be loke copy URL to clipboard oye ko ri bi: ``` git clone https://github.com/oruko yin/first-contributions.git ``` ibi `oruko yin` ni oruko githubu accounti yin. ni bi yi en didako awon akoonu ' first-contributions repository in GitHubu' si ero ise yin. ## ṣẹda ẹka seda eka si ero, amo ko to sebe te pipaṣẹ yi si ibe ``` cd first-contributions ``` oya seda eka si pelu ' `git checkout` pipase: ``` git checkout -b ``` fun apere: ``` git checkout -b add-luke-oliff ``` (kon se dadun ki e lo "add", amo o daa fun irun nnkan bayii) ## Ṣe awọn ayipada to ṣe pataki 'n ṣe awọn ayipada yẹn oya shi faili `Contributors.md` ninu olootu ọrọ, fi oruko re mo awon oruko to 'n wan be, ma fe se akoko tabi igbeyn, fi si arin. git status to ba te pipase `git status` si ebute re, wa re awon ayipada ti ose fi won mo eka ti ode pelu pipase yii `git add`: ``` git add Contributors.md ``` oya dawon papop pelu pipase yi `git commit`: ``` git commit -m "Add to Contributors list" ``` yi `` pada si oruko re. ## Titari awọn ayipada si GitHub te pipase yi `git push`: ``` git push origin ``` yi `` pada si orku e da ti ese ni ibere ## Fi yer ayipada fer awotẹlẹ Ti o ba lọ t' yer ibi ipamọ lori GitHub, iwọ yoo ri a `Compare & pull request` botini. te botini yen. create a pull request oya fi silẹ. submit pull request To ba ya a ma so gbogo yipada ti e se papo, e o gba iwifunni lori imeeli yin ## Nibo ni lati lọ? Ku ise oti pari boṣewa bisesenlo _fork -> clone -> edit -> PR_ bisesenlo ti o ma bapade ni ise asowopo Ṣe ayẹyẹ ilowosi yer 'ki o pin pẹlu' awọn ọkan ati awọn ọmọlẹyin nipasẹ lilọ’ si [web app](https://roshanjossey.github.io/first-contributions/#social-share). Ẹ lè darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ òṣìṣẹ́ wa tí kò já fáfá tí ẹ bá nílò ìrànlọ́wọ́ èyíkéyìí tàbí kí ẹ lè gba àlọ́ kankan. [Darapo](https://join.slack.com/t/firstcontributors/shared_invite/zt-1hg51qkgm-Xc7HxhsiPYNN3ofX2_I8FA). Bayi jẹ ki a bẹrẹ pẹlu' idasi' t' awọn iṣẹ akanṣe miiran. A ti ṣe akojọpọ awọn iṣẹ akanṣe pẹlu awọn ọran irọrun ti o le bẹrẹ. Ṣayẹwo [awon re](https://roshanjossey.github.io/first-contributions/#project-list). ### [Ptu le ka](../additional-material/git_workflow_scenarios/additional-material.md) ## Tutorial lilo 'miiran Irinṣẹ | GitHub Desktop | Visual Studio 2017 | GitKraken | VS Code | Sourcetree App | IntelliJ IDEA | | --- | --- | --- | --- | --- | --- | | [GitHub Desktop](../gui-tool-tutorials/github-desktop-tutorial.md) | [Visual Studio 2017](../gui-tool-tutorials/github-windows-vs2017-tutorial.md) | [GitKraken](../gui-tool-tutorials/gitkraken-tutorial.md) | [Visual Studio Code](../gui-tool-tutorials/github-windows-vs-code-tutorial.md) | [Atlassian Sourcetree](../gui-tool-tutorials/sourcetree-macos-tutorial.md) | [IntelliJ IDEA](../gui-tool-tutorials/github-windows-intellij-tutorial.md) |